text/microsoft-resx
2.0
System.Resources.ResXResourceReader, System.Windows.Forms, Version=4.0.0.0, Culture=neutral, PublicKeyToken=b77a5c561934e089
System.Resources.ResXResourceWriter, System.Windows.Forms, Version=4.0.0.0, Culture=neutral, PublicKeyToken=b77a5c561934e089
TI GBA ERUKU

Iye ti o jẹ fifiransẹ kere ju owo ti o yẹ lọ fun didapada fun ọ, eyi ti o jẹ {0:N2} microcoins. Owo ti o firansẹ ni a npe ni "eruku" ni bayi lori nẹtiwọki bitcoin, ati pe ko jẹ gbigbe mọ.

Fi iye ti o ga si ranṣẹ lati ṣe idanwo echo.
Eyi jẹ koodu QR fun idanwo echo bitcoin fun gbogbo iṣàgbékalẹ̀ Swarmops yii, kii ṣe fun {0} nikan. Ka lati inu apo owo bitcoin foonu rẹ lati ṣe idanwo echo naa, tabi firanṣẹ lati ori kọmputa rẹ taara si [{1}] (iyen jẹ Adirẹsi Bitcoin Cash). Iye naa (ayọkuro owo awakusa ti o je {2:N2} microcoins) ma jẹ didapada fun ọ ni iṣẹju aaya diẹ ti o n bo.
The {0} is the organization name. {1} is the bitcoin address for donations.
Ti gba {2:N2} microcoins ({0} {1:N2}). N pada.
{0} is native currency, {1} is amount in native currency
Ti gba {0} microcoins ("bits"). N pada.
Used if Bitcoin Cash is the org native currency.
Eyi jẹ idanwo echo bitcoin. O ma n ṣe idanwo fun hotwallet. Ti o ba fi owo kekere ranṣẹ sibi, o ma jẹ didapada fun ọ, pelu ayọkuro owo ifi idunadura ranṣẹ pada (lọwọlọwọ jẹ {0:N2} microcoins).
Idanwo Echo Hotwallet ti Bitcoin Cash
Nduro fun idunadura...
Ti ri idunadura, n se idaniloju...
Idanwo Echo Bitcoin ti Swarmops
Isafarawe Ti Nṣiṣẹ
Visible on Dashboard
O ni akoko isafarawe ti nṣiṣe lọwọ bi {0}. Pari isafarawe.
Visible on Dashboard. {0} is the impersonated name.
SAFARAWE ENIYAN?

Eyi ko wa fun mimu ni yẹpẹrẹ, ati pe ti o ko ba ṣe eyi fun awọn idi imọran ẹrọ, o tun le lodi si ofin didale ori awọn ofin ibile.

Idi ti irinṣẹ yii ni lati ṣatunṣe awọn aiṣedeede imọ-ẹrọ. Ohun gbogbo ti wa ni igbasilẹ.

Tesiwaju?
ISAFARAWE DOPIN

Isafarawe dopin ni {0:HH:mm} UTC. O n ṣe bi ara rẹ lẹẹkansi.
{0} will be fed with a DateTime. The colon is rewritten automatically into the current DateTimeFormatInfo.TimeSeparator.
ISAFARAWE DI KIKỌ

Ko yẹ ki o se isafarawe ẹnikan ti o jẹ oluṣakoso rẹ gangan.
ISAFARAWE DI KIKỌ

Ko yẹ ki o se isafarawe ẹlomiran pẹlu iwọle ipele ilana.
O nilo lati yan eniyan ti o ma safarawe.
Ti o ba nilo lati se isafarawe ara rẹ, a daba pe ki o jade kuro ni Swarmops ki o si wa iru iranlowo miiran.
ISAFARAWE DI KIKỌ

O dabi pe o ko ni awọn anfaani ti o to lati se isafarawe elomiran.
Se isafarawe olumulo miiran
Se isafarawe
Eniyan ti o ma se isafarawe rẹ
ISAFARAWE NSISE

Isafarawe bẹrẹ ni {0:HH:mm} UTC. Eyi ni Dasibodu bi eniyan ti o safarawe rẹ ma se ri.
{0} will be fed with a DateTime. The colon is rewritten automatically into the current DateTimeFormatInfo.TimeSeparator.

Irinṣẹ isatunṣe yii gba ọ laaye lati se isafarawe ti olumulo miiran lati ri ati ni iriri Swarmops bi ti wọn nigbati o ba wọle.

IKILO: Eyi jẹ irinṣẹ irẹburu gíga ti o yẹ ki o lo fun idagbasoke imọ ẹrọ ati atilẹyin ti o nilo nikan. Lilo eyi ko yẹ ki o jẹ mimu ni yẹpẹrẹ.

Gbogbo awon isafarawe ti wa ni igbasilẹ titlai, gbogbo ati eyikeyi awọn igbese ti o je gbigbe nigbati isafarawe waye ni o wa fun awari bi ti bẹẹ, atipe olumulo ti won safarawe rẹ ma gba alaye nipa irẹburu naa.

Awon ajafeto ma je pipe
(kose lo)
Awọn ti ko di ọmọ ẹgbẹ n jẹ
Ajo ipele-ipile
Ọmọ ti {0}
"Create org as..."
Ṣẹda ajo tuntun bi...
Orukọ ajọ ko le jẹ ofo. (O nilo lati fun ajọ tuntun naa ni orukọ kan!)
O le ṣẹda ajọ tuntun kan boya bi ajọ tuntun kan ti o daduro, tabi bi ọmọ si ti ajọ eyi ti o wa lọwọlọwọ yii. (Gbogbo eniyan ti o ni ojuse ninu ajọ obi kan ti ni iru awọn ẹtọ ati awọn anfaani wonyi ninu gbogbo awọn ọmọ rẹ.)
Orukọ Ajọ Tuntun
Owo iṣiṣe
Orukọ ajọ tuntun naa
Ṣẹda Ajo Tuntun
Awọn eniyan regula ma je pipe
This can be "members", etc.
Ajọ naa tuntun ti jẹ ṣiṣẹda. A ti fun ọ ni {0} alainipari ninu ajọ naa, ati pe a gbe ọ si ipo alakoso giga julọ fun akoko yi naa, nitori ki o le ṣiṣẹ pẹlu rẹ ati ṣeto rẹ daradara. Lati seto ajọ tuntun naa, lo panẹẹli iṣakoso yii (pada wa labẹ Iseto Abojuto / Ajọ).
The {0} is membership, employment, citizenship, residence, etc.
Ipo akọle atilẹba ni ibẹrẹ
Ti iṣowo
Ijọba
Alailere
nọmba ti {0}
The {0} is the membership, ambassadorship, etc.
Ibudo Awọn lẹja Ṣiṣi
Ṣatunse Ajọ
Awọn eniyan di {0} ti
The {0} is member, ambassador, etc. in the gender neutral plural.
Awọn eniyan di {0} nigbati
The {0} is member, ambassador, etc. in the gender neutral plural.
{0} pari nigbati
The {0} is membership, ambassadorship, etc.
Iye owo {0} Ni ibẹrẹ (ni {1})
The {0} is membership, etc. The {1} is the operating currency.
Ọkan {0} gbẹhin
The {0} is membership, ambassadorship, etc.
Akoko isọdọtun bẹrẹ lati
Seranti lati sọdọtun
Awọn isọdọtun kan
(options: all organizations, one org at a time)
Iye owo isọdọtun (ni {0})
The {0} is the operating currency (USD etc).
Ibudo Ti ara ẹni ti Ajọ
Awọn ipo Alakoso Fun {0}
The {0} is the org name.
Awọn ipo Ibile (Nibi gbogbo)
Iwe isanwo Oṣiṣẹ
Awọn ipo Pataki Fun {0}
The {0} is the org name.
Awon olujọwọ ara ẹni Nduro fun Idahun
Ṣeto eto igbaosise fun ajọ yii, bakanna pẹlu igbaoṣiṣẹ rẹ ni awọn ipele (igbimo) ati alakoso (Ipele-C tabi deede) pataki. O tun le ṣakoso awon olujọwọ ara ẹni ti o n duro ati iwe isanwo lati ibi.
Igbaoṣiṣẹ si Ajọ
Awọn iwifunni Alabojuto Lati Adirẹẹsi
Awọn iwifunni Alabojuto Lati Orukọ
Ibori Orukọ agbalejo Backend
Ibudo SMTP gbọdọ jẹ nọmba. Ko le yanju agbalejo:ibudo.
Ko le yanju olumulo, yege, agbalejo, ati / tabi ibudo. (Agbalejo nikan ni o nilo.)
URL ti o se wo lati ita
Awọn eto Itan kaakiri Ifiweranṣẹ
Awọn alakoso Eto
Awọn eto imọran ẹrọ oriṣiriṣi fun iṣàgbékalẹ̀ Swarmops yii. Ko je pato si eyikeyi ajọ tabi eniyan, ṣugbọn gbogbo iṣàgbékalẹ̀.
Orukọ Iṣàgbékalẹ̀
Awon eto Ilana
Iṣakoso SMTP (olumulo:yege@agbalejo:ibudo)
Swarmops ti fi meeli ayẹwo kan ranṣẹ si ọ lati se idaniloju awon eto isakoso SMTP tuntun rẹ.
O yẹ ki o lo HTTPS nikan fun iru aaye ayelujara bii eyi. Ṣugbọn o ti mọ eyi tẹlẹ, ṣe o ko mọ?
Ibudo WebSocket (Backend)
Ibudo WebSocket (Frontend)