text/microsoft-resx
2.0
System.Resources.ResXResourceReader, System.Windows.Forms, Version=4.0.0.0, Culture=neutral, PublicKeyToken=b77a5c561934e089
System.Resources.ResXResourceWriter, System.Windows.Forms, Version=4.0.0.0, Culture=neutral, PublicKeyToken=b77a5c561934e089
Owo Agbaalẹ #{0:N0} fun {1} ti jẹ fifọwọsi fun {3:N2}.
Status message.
Ifọwọsi fun Owo Agbaalẹ #{0:N0} fun {1} jẹ FIFAGILE. Ko ni jẹ sisanjade ayafi ti o ba di fifọwọsi lẹẹkansi.
When somebody undoes a previous approval.
O ko le fọwọsi iye yii. Isuna naa jẹ ofifo fun ọdun {0}.
O ko le fọwọsi iye odi.
O ko le fọwọsi iye odo.
Ma binu, o ko le ṣe atunṣe isuna owo ise sisanjade.
Eyi ko dabi pe o jẹ iye ti o fẹsẹmulẹ. Jọwọ tun gbiyanju?
Jowo mu isuna kan lati ṣe atunṣe afojusun idiyele naa fun.
Ibéèrè owo agbapada #{0:N0} lati {1} fun {2} {3:N2} ti jẹ fifọwọsi.
{2} is the currency.
Ifọwọsi fun Ibeere Owo Agbapada #{0:N0} lati {1} jẹ FIFAGILE. Ko ni jẹ sisanjade ayafi ti o ba di fifọwọsi lẹẹkansi.
When somebody undoes a previous attestation.
Igbese
Yes / No buttons. Keep short!
Olujanfani
The receiver of money.
Isuna
Apejuwe
Awon iwe
Button to see underlying documentation. Keep short!
Nkan
Could also be translated to "Type". Will list"cash advance", "invoice", etc.
Di bibeere
Header for the requested amount.
Awọn owo ti o nduro fun ifọwọsi rẹ
Eyi ni ibi ti o ti ṣe ifọwọsi awọn owo ti awọn eniyan miiran n beere lati inu awọn isuna rẹ. Ohun kankan koni jẹ sisan ṣaaju ki o to fọwọsi.
Iwe iye-owo ọja #{0:N0} lati {1} fun {2} {3:N2} ti jẹ fifọwọsi.
{2} is the currency.
Ifọwọsi fun Iwe iye-owo ọja #{0:N0} lati {1} jẹ FIFAGILE. Ko ni jẹ sisanjade ayafi ti o ba di fifọwọsi lẹẹkansi.
When somebody undoes a previous approval.
Fọwọsi
keep short
Fọwọsi
Kọ
keep short
Atunse isuna
keep short
Mo kọ aṣẹ rẹ fun owo nitori...
This is a Monty Python reference. When translating, translate to "I am denying your request for funds because..."
(Iye naa ko gbọdọ ni eyikeyi VAT ti a ti da sọ!)
This refers to when a budget owner is asked to correct an amount to charge their budget, based on seeing an invoice or receipt for that charge, and is instructed that they should not enter the TOTAL as shown on the invoice or receipt, but the TOTAL EXCEPT VAT.
Kini iye ti o n jẹrisi dipo (in {0})?
The {0} is the organization currency (SEK, USD, µBTC etc).
Yi nkan yii pada si iye yii (in {0}), lẹhinna jẹrisi bẹ yẹn:
Idi ti o yan fun ẹkọ si olufisilẹ naa:
Gbe idiyele naa lo si iṣuna yi dipo:
Satunṣe awọn isoro tabi kọ ifọwọsi
Mo ma fọwọsi eyi, ṣugbọn fun iye ti o yatọ.
Iye naa ko tọ. Mo ma fọwọsi fun iye ti o tọ.
Mi koni fọwọsi akọsilẹ yii. O ti bajẹ.
This is a Monty Python reference. When translating, translate to "Deny attestation of this record altogether."
Akọsilẹ yii yẹ ki o se idiyele isuna ti o yatọ. Gbe lo sibẹ.
Kini o dabi iṣoro pẹlu akosilẹ yii?
Ko si awọn owo ti o to to ṣẹku ninu isuna naa lati fọwọsi iye owo yi.
Ko si awọn owo ti o to lati fọwọsi eyi. O le jẹri to {0} {1:N2} diẹ sii ninu isuna yii fun ọdun naa {2}.
The {0} is the currency and the {1} is the remaining budget. The {2} is the current year.
ITAYỌ ISUNA?

Ko si awọn owo ti o to to ṣẹku ninu isuna naa lati fọwọsi inawo yi. Ni deede, yoo jẹ didena lati ni ifọwọsi. Sibẹsibẹ, o le bori idaduro yii ati ki o ni ijẹri sibẹsibẹ, nitorina o jẹ ki akọọlẹ naa tayọ isuna rẹ.

Ṣe o fẹ lati fọwọsi inawo naa, nitorina fi ipa se itayọ, tabi ṣe o fẹ fagilee, duro lori isuna dipo?

Duro lori Isuna
Fipa Se itayo
ISUNA JE TITAYO.
The UPPERCASE is intentional.
Fọwọsi Awọn iye owo
Apero #{0:N0}, je tito nipasẹ {1}, ti jẹ fifọwọsi fun {3:N2}.
Ifọwọsi funApero #{0:N0} nipasẹ {1} jẹ FIFAGILE. Ko ni jẹ sisaami isanjade si ayafi ti o ba di fifọwọsi lẹẹkansi.
When somebody undoes a previous approval.
Owo ise #{0:N0} fun {1} ti je jijeri fun {3:N2}.
Ifọwọsi fun Owo isẹ #{0:N0} fun {1} jẹ FIFAGILE. Ko ni jẹ sisaami isanjade si ayafi ti o ba di fifọwọsi lẹẹkansi.
When somebody undoes a previous approval.
IKILỌ: ISUNA TI KO LETO

Iye owo ti o n fọwọsi jẹ ti akọọlẹ kan ninu lẹja ti ko ni eni ti o ni ati pe ko ni eto owo isuna ti a ṣeto fun ọdun naa. Ro sisàbẹwò si Atẹ ti Awọn Akọọlẹ naa ati yiyan awọn isuna fun awọn ohun ti nwọle ati awon inawo ti a n reti.

Ifiranṣẹ yii yoo ma han ni ẹẹkan fun ibẹwo si Awọn ifọwọsi Iye owo.

Apapọ Iye iwe iye-owo oja (ni {0})
{0} is the organization's main currency.
Ara VAT ti apapọ ({0})
Ṣẹda
Could also be "file" (as verb, about the invoice) or equivalent
Apejuwe
Free-text description of invoice
Aworan Iwe iye-owo oja
Awọn alaye Isanwo
Displayed as header over supplier's account details
Eyi ni ibi ti o ti n se apamo awọn iwe iye-owo oja ti o gba ni ajo rẹ ("Awon akọọlẹ tole sanwo"). Tẹ orukọ olupinfunni, iye, ojo tito, itọkasi iwe iye-owo oja naa, ati gbe aworan iwe iye-owo oja si. Bakannaa, mu isuna kan. Eni ti o ni isuna nilo lati jẹri, bi tele. (Awọn amugbooro ojo iwaju ti a ma sẹ si eto yii yoo ni awọn ibeere rira ati awọn akojo olupinfunni.)
Iwe iye-owo oja ti nwọle ti o gba
Itọkasi Iwe iye-owo oja
OCR / Alaifọwọyi
Some invoices come with OCR numbers printed on them for automatic processing.
Afowoyi
Other invoices come without automated processing and a manual
Iwe iye-owo oja ti nwọle #{0:N0} je gbigbe dide.
The {0:N0} is just an identity number (formatted for culture). This message is displayed on success.
Akoole
Free text input, intended to convey everything needed to get the money right
Gbe faili aworan ga
Jowo tẹ akoole banki ti olupinfunni tabi deede.
Jowo tẹ iye owo naa (ninu {0}) ibeere iwe iye-owo oja naa.
Jowo mu pato isuna kan ti o ma gba idiyele.
Jọwọ sagbega ọkan tabi jubẹlo awọn iwe ti ojulowo iwe iye-owo oja.
Jowo mu aṣayan kan.
Jọwọ ṣe apejuwe ohun ti rira yii je.
Ṣiṣẹda Iwe iye-owo oja ti o njade
Ṣẹda
This goes on a button, so needs to be short (8-9 letters max)
Ṣiṣẹda Iwe iye-owo oja ti o njade
Iwe iye-owo oja ti njade #{0:N0} je gbigbe dide.
Eyi jẹ koodu QR fun awọn itọrẹ si {0}. Ka lati inu apo owo bitcoin foonu rẹ lati ṣe itọrẹ, tabi ṣe itọrẹ lati ori kọmputa rẹ taara si [{1}] (eyi ni adirẹẹsi Bitcoin Cash).
The {0} is the organization name. {1} is the bitcoin address for donations.
Gba {0} {1:N2} ({2:N0} microcoins tabi "bits"). O Se!
{0} is native currency, {1} is amount in native currency
Awon owo je gbigba ({0})
The {0} will be replaced with currency name.
Gba {0} microcoins ("bits"). O se!
Used if BTC is the org native currency.
Ti o ba fẹ lati ṣe itọrẹ si ajo naa, o le ṣe bẹ nibi.
Se itọrẹ
Nduro fun idunadura...
Ti ri idunadura, n se idaniloju...
Itọrẹ si {0}
The {0} is the organization name
Eyawo si {0}
The {0} is the organization name
Iye ibeere owo agbapada (ni {0})
{0} is the currency.
Nọmba Akọọlẹ
Nọmba Imukuro
Oruko Banki
Isuna
Béèrè
Could also be "file" (as verb) or equivalent
Iru iye
This is the 2nd bookkeeping dimension.
Apejuwe
Gbe Expensify CSV ga

ASISE: Ko le yanju Expensify CSV. Ti eyi ba jẹ faili CSV lati Expensify, nigbanaa Swarmops nilo awọn ipin "Akoko", "Iye", "Oniṣòwo", "Asọye", "Ẹka", "MCC", "Ojulowo Owo", ati "Ojulowo Iye" to ma wa ninu faili naa. Ti ajo naa ba ma n se ijabọ VAT, ajewipe a nilo ipin kan si ti a npe ni "VAT".

Ko le tẹsiwaju pẹlu faili yii.

Do not translate the Expensify column field names.

ASISE: Faili CSV Expensify ko ni awon aaye data ti a nilo. Faili naa han lati ma ni o kere ju ọkan ninu awọn aaye profaili atilẹba CSV Expensify ti a nilo. Kansi awọn akọsilẹ iwe imọ ẹrọ ati ki o ṣe afiwe rẹ pẹlu faili ti o gbiyanju lati gbe ga. (O jẹ idi ti o sunmọ julọ lati fa aṣiṣe, dajudaju, pe o gbiyanju lati gbe faili ti ko tọ rara si – boya aworan kan dipo Expensify CSV – ati pe eyi ni idi fun awọn data ti a n reti ti kosi nibe.)

Ko le saayan faili yii.

ASISE: Faili CSV Expensify ko ni aaye VAT. Niwon ti ajọ yii ma n jabọ owo ori alafikun iwulo (VAT) si awọn alase, eyi gbọdọ da lori inawo ọkọọkan. Jowo mu ki VAT sise ni Expensify ki o si ṣẹda profaili ifiranṣẹ CSV tuntun kan ti o n fi eyi ranse labẹ ipin akọle "VAT". Ti ẹgbẹ rẹ bati ṣẹda irufẹ profaili CSV yii, o kan le nilo lati yan nigba ti o ba n firanṣẹ si CSV.

Ko le saayan faili yii.

Ti o ba ni awọn ijabọ inawo pupọ, o le kó wọn jọ pelu Expensify ati ki o sagbega ijabọ Expensify CSV kan nibi (ti o gba lati Expensify labe Awọn ijabọ, Firanṣẹ, bi CSV). Swarmops ma lo Expensify lati gba gbogbo ọkọọkan awon iwe oja ati kiiko won sile lọtọ bi awon ibéèrè owo agbapada fun iṣiro pipe.
Fun eyi lati ṣiṣẹ, niwonti {0} njabo VAT si awọn alaṣẹ owo ori, o ma nilo lati sayipada profaili atilẹba Expensify CSV lati fi VAT kun, eyi ti atilẹba ko ṣe. Awọn oju ewe iranlọwọ Expensify ni diẹ sii lori bi eyi ṣe le je ṣiṣe ati pe ti o ba n lo Expensify NI ilana ẹlẹgbẹ, eto imulo Expensify yin gbọdọ ti ni profaili ifiranṣẹ CSV ti oni imusise VAT tẹlẹ.
{0} is the organization name.
Dida lori awọn eto ajo naa, profaili ifiranṣẹ "CSV Atilẹba" naa ni Expensify yẹ ki o to fun Swarmops.
Gbogbo awọn ibéèrè owo agbapada nilo isuna ṣaaju fifiṣilẹ.
This is displayed after the user has uploaded an Expensify report with lots of expense claims, but hasn't yet set a budget for all of them
Ko si awon itan akọọlẹ Expensify lati fisilẹ
This appears after an empty file is uploaded, or the last record deleted
Owo ijabo Expensify jẹ
Ṣetan lati fi ibeere kan sile
Ṣetan lati fi ibeere {0} sile
The {0} is replaced by a number, 2 or higher
Ibeere gbigbe dide ni aseyori.
Aseyori awon ibeere {0} gbigbe dide.
Gbe Faili CSV Expensify Miiran ga?
Displayed after upload of the first file, so "another" means "a second (third, fourth...) file", as opposed to "a different file". French "encore un fichier", German "eine weitere Datei", Scandinavian "en fil till", etc.
ara mi
Eyi jẹ ibéèrè owo agbapada lati ọdọ tani?
Awọn alaye Banki Rẹ
Aworan Iwe oja
Ti o ba ti ṣe rira ni ipo ajo naa nipa lilo awọn owo ti ikọkọ re, iwo yoo fẹ idapada owo fun eyi nipa sisagbe dide ibéèrè owo agbapada. O ma ṣe eyi nipase gbigbe awọn iwe oja ga ati mimu isuna ti o yẹ ki idiyele na lo. Ti o ba ti gba owo agbaalẹ tẹlẹ fun rira yii, eyi ni ibiti o ti yọ gbese ajo naa si ọ kuro nipa fifi awon iwe oja silẹ.
Beere Owo Pada Fun Inawo
Ibéèrè owo agbapada kan ti di gbigbe dide pelu aseyori fun {0} {1:N2} ni ilodi si isuna ti{2}.
Awọn iwe oja naa yoo nilo lati di jijẹri ati pe ibeere naa yoo nilo lati di jijẹri nipasẹ ẹniti o ni isuna naa.
{0} is the currency, {1} is the amount, and {2} is the budget name.
Ni kete bi eyi ba ti ṣẹlẹ, awọn owo naa yoo tẹsiwaju si sisanjade si akoole rẹ ti o tokasi.
Bi o ti se jepe isuna ara re ni, ijẹrisi ti pari tẹlẹ. Ifọwọsi nikan lo jẹ pataki.
Gbe Ijabo Expensify ga Fun Idapada owo
Gbe Awon aworan Iwe oja ga
Jowo tẹ iye owo naa (ni {0}) ti o n beere fun.
Jọwọ sagbega ọkan tabi jubẹlo awọn aworan iwe oja ti o n se atilẹyin ibéèrè owo agbapada.
Jowo mu aṣayan kan bi a ṣe tọkasi.
Very general as tags may be many things.
Jọwọ ṣe apejuwe ohun ti rira yii je.
VAT ti apapọ ({0})
Kikojọ awọn iwe iye-owo oja ti nwọle
Olufiranse iwe iye-owo oja
Eyi se akojọ 100 awọn iwe iye-owo oja ti o tuntun julọ, ti a to lẹsẹsẹ nipasẹ ọjọ titọ pẹlu tuntun julọ lakọkọ.
Awọn iwe iye-owo oja ti nwọle
Ti firanse
Onibara
Kikojọ awọn Iwe iye-owo oja ti njade
Eyi se akojọ 100 awọn iwe iye-owo oja ti aipẹ julọ, ti a to lẹsẹsẹ nipasẹ igbati wọn je siseda, tuntun julọ lakọkọ.
Gbogbo Iye
Ojo titọ
Sakojọ Awọn Iwe iye-owo oja ti njade
...ati eyi
AutomationStartFirst and AutomationStartNext are shown as labels to machine-readable data fields, that the user can scan with an app in their smartphone.
Yaworan eyi
AutomationStartFirst and AutomationStartNext are shown as labels to machine-readable data fields, that the user can scan with an app in their smartphone.
Iye
Amount to be paid out
Owo, Ọna
"Method" refers to the method of payout -- wire transfer, direct deposit, giro service, etc.
Ti san
Possibly in imperative; a click in this column indicates payment has been done. It is an action column, not an information column.
Sanwo
Like the "Actions" column in other grids, but just with one option, "Pay this expenditure"
Olugba
Can be org (for invoice) or person (for salary, expense, advance)
Itọkasi
Depends on cost type - can be an OCR number for an invoice, a cash advance number, a salary spec, etc.
Awọn owo Ṣetan Fun Sisanjade
Awọn wọnyi ni awọn ọna pupọ ti awọn owo si ajo ti o ti kọja gbogbo awọn idiwo fun sisanjade. Wọn ti ṣetan lati je sisan jade fun olugba naa. Eyi ni ibi ti o ti samisi wọn gegebi pe o ti je sisan jade (boya nigbati o ba jẹki banki rẹ jẹ sisi ni akoko miran).
Eyi ti jẹ Sisan
As in "Confirm The Currently Displayed Payout Has Been Manually Executed" -- try to keep short, "This is Paid" length is ideal
Owo ati Iye
Will be a label for something like "USD 10,000.00"
Yanju Isanwo Yii ni Atọwọda Nisinyii
Displayed as header over the details of a payment to be made manually (as opposed to with bitcoin/crypto)
Ṣe o ma yaworan isanwo yii?
In longer form, the question would be "Are you using a mobile phone or other device to capture this payment data automatically?". Some banking apps can scan QR codes or specially formatted number sequences.
Fihan ni ọna ti o se ka fun ẹrọ
Don't make this string much longer than it is.
Ọna Gbigbe kiri
As in "money transfer method"; this can be a domestic bank transfer, mailing a check, et cetera.
Safihan OCR fun awọn ohun elo alagbeka
Safihan awon isanwojade ti o sii sile ({0:N0})
These are payouts that have been ordered, but aren't yet mapped to actual transactions. Can be shown for the purpose of undoing them if they were wrong.
San Owo Jade
Isanwo ti pẹ
"Late" in this context means "after its due date".
Ko le fagile isanjade #{0}: o ti yanju tẹlẹ tabi je pipade.
Isanjade #{0:N0} si {1} jẹ siṣẹda.
Written as log message when the user confirms a payout has been made.
Isanjade #{0:N0} je fifagile ati pe ohun gbogbo je didapada.
Owo ori Afikun
If applicable, translate to local legal tax term
Owo ori Iyokuro
If applicable, translate to local legal tax term
Apapọ Owo oya
Wo awọn iwe owo ori (awọn fọọmu owo ori ti o ti pari) fun iwe isanwo ajo naa, eyi ti o rọrun fun ọ lati daakọ si awọn fọọmu owo ori rẹ gangan, tabi boya tẹjade paapaa bi o ṣe wa.
Iṣẹ-ṣiṣe ati awọn fọọmu gangan yatọ nipasẹ orilẹ-ede ati nigbamiiranma da lori koodu third-party ati awon plugin.
Awọn fọọmu Owo ori Iwe isanwo
Awọn fọọmu Owo ori Oṣooṣu Fun {0} Fun
The {0} is the organization name. A country selector follows (imagine a "France" tacked on to the end).
Apapo Iye
Apapo Owo ori
Iye agbaalẹ (ni {0})
{0} is the currency.
Nọmba Akọọlẹ
Nọmba Imukuro
Oruko Banki
Isuna
Béèrè
Awọn alaye Banki Rẹ
Ti o ba jẹpe o ti fẹ ṣe rira ni ipo ajo naa, ṣugbọn nilo owo ni agbaalẹ dipo ki o beere rẹ pada lẹhinwa, o le beere owo agbaalẹ fun idi pataki kan.
Beere Owo Agbaalẹ
Idi
Ibeere owo agbaalẹ kan ti jẹ bibere fun {0}. Iye ti o jẹ bibere fun ni {2} {3:N2}. Kiyesi pe eyi jẹ eyawo lati ajo naa titi ti awọn iwe oja a fi jẹ gbigbekalẹ.
{0} is the person receiving the advance, {1} is the entered description. {2} is the currency (in caps) and {3:N2} is the amount, with two decimals, displayed in culture.
Eyi nilo lati jẹ fifọwọsi nipasẹ ẹniti o ni isuna naa lẹhinna o ma tẹsiwaju lati sanwojade.
Bi o ti se jepe isuna ara re ni, eyi ti jẹ fifọwọsi alaifowoyi ati pe o ti tẹsiwaju si isanwojade.
This is displayed if either the person creating the cash advance OR the person receiving it is the budget owner.
Jowo tẹ iye owo naa (ni {0}) ti o nifẹ lati gbaalẹ.
{0} is the currency.
Jowo tẹ nọmba akoole banki re.
Jowo tẹ nọmba imukuro banki re.
Jowo tẹ orukọ banki re.
Jowo mu isuna kan ti o ma gba idiyele.
Jọwọ sọ idi owo agbaalẹ naa.
Awon iwe oja ti o n duro de ijerisi re
Eyi ni ibi ti o ti ma n ṣayẹwo ati jẹrisi ifẹsẹmulẹ awon iwe oja ti o tẹle awọn ibéèrè owo agbapada. Ṣayẹwo pe iye naa tọ ati pe awon iwe oja naa wa fun ohun ti o sọ pe o wa fun.
Se ijẹri awon iwe oja
Ijẹrisi awọn iwe ọja fun Ibéèrè Owo agbapada #{0:N0} fun {1} {2:N2} ti jẹ FIFAGILE. Ibéèrè owo agbapada naa koni tẹsiwaju si isanjade ayafi ti o ba jẹ atunjẹri.
Awon iwe oja fun Ibéèrè Owo agbapada #{0:N0} fun {1} {2:N2} ti je jijerisi.