text/microsoft-resx
2.0
System.Resources.ResXResourceReader, System.Windows.Forms, Version=4.0.0.0, Culture=neutral, PublicKeyToken=b77a5c561934e089
System.Resources.ResXResourceWriter, System.Windows.Forms, Version=4.0.0.0, Culture=neutral, PublicKeyToken=b77a5c561934e089
fi akọọlẹ kun
Displayed as link in parens after account group name
Ṣẹda akọọlẹ ipilẹ tuntun
Eyi ni akọọlẹ awọn Gbese. Iru awọn akọọlẹ bẹ saba ma n ni isiro ni odi, niwọn ti wọn jẹ aṣoju awọn ohun-ini odi ninu ajọ naa. Isiro iṣaaju ti o tẹ wọle tẹlẹ ti jẹ yiyipada si odi.
Orukọ Akọọlẹ
Ṣe akọọlẹ yii ṣii fun awọn iṣowo?
Nṣiṣẹ
Alabojuto
Isuna (isiro je foo bar)
foo, bar replaced on load with actual values
Se awọn eniyan le lo akọọlẹ yii fun awọn ijabọ inawo?
Ti o ṣe na
N satunkọ Akọọle
Imudaṣiṣẹ
Automatic connections to bank, blockchain etc.
Àtòpọ̀
Awọn isẹ oojọ
Isiro Iṣaaju (ti o nwole sinu {0}), {1}
{0} is the first ledger year in Swarmops. {1} is the currency code.
Akọọle Obi tabi egbe
Eyi jẹ Akọọlẹ Awon inawo. Iru awọn akọọlẹ bẹẹ saba ma n ni isuna ni odi, niwọn ti wọn fa adinku awọn ohun ini lati inu ajọ. Isuna ti o gbero je yiyipada si odi.
Displayed as a message box
Akoole
Isiro
Isuna
Ṣatunkọ
Awọn asia
Eyi ni àpapọ alaye awọn iroyin iṣowo ti inu iwe leja iṣowo rẹ. O le ṣe itọju diẹ lati ibi, ti o ba tun je pe ọpọlọpọ awọn iṣẹ ojoojumọ jẹ pinpin si awọn eniti o ni isuna.
Akọọlẹ tuntun
the name of newly-created accounts, before rename
Safihan Awọn akọọlẹ ti Koṣiṣẹ({0:N0})
The {0} is the number of inactive accounts.
Atẹ ti Awọn Akọọlẹ
Ipadanu ti a Fojusun {0}
"Projected" as in "Budgeted". {0} is year.
Ere ti a Fojusun {0}
"Projected" as in "Budgeted". {0} is year.
Akoole
Awọn ohun ini XXXX
For the simplified view - XXXX is replaced with year
(ayipada)
Change from previous year's close, which is same as from start of this year
Balance Sheet fun {0},
{0} is the organization name. The year follows immediately, so keep ending comma.
Lọwọlọwọ
BalanceSheet
Must ONLY contain A-Z, a-z characters - nothing accented!
Ipari-XXXX
The XXXX is replaced with year number.
Balance Sheet jẹ àpapọ alaye awon ohun ini ati awọn gbese ni aworan kan ni logan, ati pe o ma n je lilo lati wo bi awọn esi yoo ṣe ni ipa lori ilera iṣowo owo ti ajo naa. O tun le fẹ lati wo ikede ere atiadanu eyi ti o jẹ àpapọ alaye ti owo ti o wole ati inawo.
Balance Sheet jẹ àpapọ alaye awon ohun ini ati awọn gbese ni aworan kan logan, ati pe o ma n je lilo lati wo bi awọn esi yoo ṣe ni ipa lori ilera iṣowo owo ti ajo naa. O tun le fẹ lati wo balance sheet ti o gasi fun alaye diẹ sii, tabi ikede ere atiadanu eyi ti o jẹ àpapọ alaye ti owo ti o wole ati inawo.
Awọn gbese XXXX
For the simplified view - XXXX is replaced with year
(ayipada)
Change from previous year's close, which is same as from start of this year
Adanu titi di ({0})
The {0} is the year of the report
Balance Sheet
Ere titi di ({0})
The {0} is the year of the report
Ayipada Q1
Ayipada Q2
Ayipada Q3
Ayipada Q4
Bẹrẹ-XXXX
The XXXX is replaced with year number.
Apejuwe isowo naa ko le wa lofo.
Iṣowo naa nilo ẹri ti rira.
Iye VAT naa ko dabi pe o jẹ titẹ ni daadaa.
Deede Awọn ibaamu Fun Iye yii
Header in selection list. Capitalize as customary for culture.
Iye to Baramu Sugbọn Ni Deeti / Aago Airotẹlẹ
Header in selection list. Capitalize as customary for culture.
Iye ti o wa Laarin Ifarada 5%
Header in selection list. Capitalize as customary for culture.
Akoole
Usually the account name. Can also be "several".
Iye
Apejuwe
Tx#
Keep VERY short.
Diẹ ninu awọn iṣowo owo ti a gbe wọle ko le ṣe sopọ pẹlu isiro alaifọwọyi ti n lọ lọwọ. Eyi ni ibiti o ti ma se asopọ alafọwọyi iru awọn isowo bẹ lati mu wọn "peye" (ti isowo kan ba ni apakan pere ti o ti pari, bi owo ti a fi ranṣẹ si ajọ ti ko ni akọsile ohun ti owo naa wa fun, a ma sọ pe isowo naa "ko peye" ati "isanwo to wa ni asorọ", ani wipe, ko si ninu akọọlẹ iwe iṣowo ikeji rẹ).
Isiro
This is a verb in the imperative form - it's on a button.
Se ibaamu iwe iye-owo oja
Baamu
This is a verb in the imperative form - it's on a button.
Baamu
Samisi bi Rira Taara
Pa ijabọ VAT de
Se imudọgba iyatọ ti o lodi si akọọle yii:
Ṣe ibaamu isowo naa si iwe iye-owo oja ti o njade:
Isowo naa baramu pelu isanwojade yii:
Isowo naa baramu pelu isanwojade owo-ajeji yii:
Iye rira ẹjawo-taara ({0})
{0} is the currency
Gbe idiyele rira lo si iṣuna yi
Gbe iwe oja tabi iwe miiran ga
Se imudojuiwọn apejuwe isowo
Ẹya ti VAT ti iye naa
Isowo yii jẹ isanwo/ipada fun ijabọ VAT yii:
Iṣowo ko peye nipasẹ +FOO,BAR.QX. Ṣe o fẹ lati...
Se imudọgba alafọwọyi si isowo yii ni ilodi si akọọle kan?
Ṣe ibaamu eyi si iwe iye-owo oja ti o njade ti o wa ni sisi?
Ṣe ibaamu eyi si iwe iye-owo oja ti o njade ti o wa ni sisi ni owo ti ko pewọn (ifarada 5% ti forex)?
Ṣe ibaamu iyatọ isowo naa si ibi isanwojade ti o wa ni ṣiṣi, ti ko ni ibaamu?
Ṣe itoka isowo naa si isanwojade owo-ajeji kan (iye ifarada {0}%)?
Ṣe ami si eyi bi rira taara-lati inu- akoole?
Pa ijabọ VAT kan de pẹlu isowo yii?
Mimu peye/Minu baramu Isowo #67890 Lati yyyy-mmm-dd
The span text is replaced runtime.
Eyi ti o ni ibaamu ju
This is the header of a match where the transaction description somehow matches the invoice reference.
(Kosi awon isanwojade ti o sii sile)
(Kosi awọn isanwojade ti o tọ fun ibaamu)
Iye ti o wa Laarin Ifarada 1%
Header in selection list. Capitalize as customary for culture.
Iwe iye-owo oja ti o njade #{0:N0} fun {1}, pari ni {2:yyyy-MMM-dd}: {3}
Argument {0} is the invoice identity, {1} the customer name, {2} the due date and {3} the invoice-currencied amount (which can be different from the org's presentation currency)
Mu peye & Mu baramu Awọn isowo
Isanwojade #{0:N0}, {5} (nreti ni{1:yyyy-MMM-dd}) fun {2}: {3} {4:N2}
0 is the payout Id, 1 is the date (do edit format if called for in culture), 2 is the recipient name, and 3 4 is the currency and amount, 5 is the specification (like "Expense Claim #4711")
-- Mu Isanwojade kan --
Iye ti o wa Laarin Ifarada 10%
Header in selection list. Capitalize as customary for culture.
Ijabọ VAT fun itayọ {1:yyyy-MMM}
Adirẹẹsi Bitcoin
Balansi microcoins
Ona Imujade
Ko si awọn owo kankan ninu hotwallet naa.
Ifọsiwẹwẹ Hotwallet
"Breakdown" as in "zooming in to more details", not as in "ceasing to function".
Eyi safihan ifọsiwẹwẹ awọn adirẹsi hotwallet ti bitcoin ti ajọ naa ati isiro. (Awọn adirẹẹsi ofifo ati awọn adirẹẹsi ti a ti lo ri ni iṣaaju ko han.)
Hot Wallet ti Bitcoin
Hash ti Isowo
Iṣowo to njade ti ko je nina
The local translation of a bitcoin UTXO (Unspent Transaction Output).
Iye {0}
The {0} is the organization currency.
Isuna vs Iye Gangan
YTD ti a reti
As in "expected actuals", as in when compared to budget. From the context, just "Expected" will also work.
Oju ewe yii n ṣe afihan ifọsiwẹwẹ ti isuna ni afiwe si ifọsiwẹwẹ ti abajade gangan titi di igba yii.
Isuna vs Iye Gangan
Financial budget vs. Actual financial outcome
Ipadanu Odọọdun
Ere Odọọdun
Ṣẹda {0}
Parameter zero is the name of the VAT report as created localized in the logic layer
Awọn ijabọ ọdọọdun
This is the header for closing of ledgers and generation of annual reports at the end-of-month routine
Owo kiripito
This is the header for various bitcoin hotwallet / cold storage operations
FO IGBEGA IWE?

Iwe yii ni a nilo fun akọsilẹ iṣẹ. Idi kan soso ti o yẹ lati fo iwe ni wipe ko wa laaye nitori pe awọn iṣẹ naa ko ti bẹrẹ iṣẹ, bii nigbati isẹ kan ba bẹrẹ ni Oṣu Keje ninu ọdun kan kii yoo ni awọn iwe fun Osu kini ti ọdun naa

A ko ni beere lọwọ rẹ lẹẹkansi lati gbe iwe yii ga ti o ba fo ni bayii.
Ilana-iṣe-ti-Ipari-Osu: {0:MMMM yyyy}
Parameter zero is the month that's just ended
Sagbega Ikede Banki ({1}) for {0} for {2}
Parameter zero is the account name, parameter one the format (e.g. PDF), parameter two is the month (e.g. October 2018)
Orukọ Akọọlẹ
Isiro peye:
Ṣẹda Iṣowo
Text on button for executing create
Deeti ati akoko ti isowo (UTC)
Apejuwe Isowo
Nṣẹda Isowo tuntun
Header of dialog
Akọọlẹ ti ila ibu isowo kini
Iye ti ila ibu isowo kini
Fi isowo tuntun kun
Option in sidebar
Apejuwe / Akoole
As in, description of a transaction OR the full name of an account
N wo / N satunkọ Isowo #67890
The transaction id is replaced client-side on display
(Kosi data idunadura)
Leja Gbogboogbo fun
This phrase is followed by dropdowns for year and month
Fi awọn ila ibu kun isowo
(you can't really edit a transaction, just add more rows to it)
Awọn alaye ti titele isowo alaifọwọyi
(this means the transaction is locked from editing)
fun
"inspect [accountdropdown] FOR [year] [month]"
Ṣayẹwo
"INSPECT [accountdropdown] for [year] [month]"
Isiro Ti nwọle
Kosi Isiro Iṣaaju
Eyi ni awọn igbasilẹ ti lẹja iwe iṣowo oniwọle-meji fun awọn inawo ti ajọ naa. O le ṣàyẹwò wọn nibi ni kikun fun awon idi iṣatunyẹwo. O n wo akọọlẹ P & L lọwọlọwọ, nitorina awọn ami wa ni idakeji - owo ti o wọle ni ami ayọkuro ti inawo ni ami afikun nitori bi iwe iṣowo oniwọle-meji ti Venetian ṣe ma n ṣiṣẹ.
N sayẹwo Isowo #12345
The transaction id is replaced client-side on display
Ibẹẹrẹ orukọ
Ti wole
Ko si awọn isowo kankan ninu akọọlẹ yii fun akoko ti o yan.
Isiro Ti njade
Isiro Ipari
Isiro Ipari (titi di akoko yi)
Displayed if the end-balance date isn't reached yet
Ṣayẹwo Awon lẹja
(Jowo mu akọọlẹ kan.)
Displayed initially and when no valid account selected
Tx#
Keep VERY short.
Ijẹrisi nipasẹ {0} ni {1:yyyy-MMM-dd}
ni idapo pelu
Inserted between transaction causes.
(alaye ni kunkun ti a dimu)
Jọwọ yan akọọlẹ kan lati le fi ila ibu kan kun isowo yii.
Iwe iye-owo oja Ti nwọle #{0:N0} lati {1}:
the {1} is the supplier name
Jẹ ṣiṣe nipasẹ {0}.
As in "payout executed by": who actually paid the money?
Oṣuwọn owo ise {0} {1:N2}, awọn atunṣe apapọ {2:+N2;-N2;none}, apapọ owo ise {3:N2}, owo ori ti o je yiyokuro {4:N2}, awọn atunṣe ojulowo {5:+N2;-N2;none}, isanwojade {6:N2}.
The "none"s in the format strings need to be translated.
Eyi ni Isanwojade #{0:N0}. O jẹ isanwojade fun
Ifọwọsi iwe nipasẹ {0} ni {1:yyyy-MMM-dd}
"Document" refers to receipts, invoices, etc.
Isowo yii se apade ijabo VAT fun {0}.
{0} will be a time period, like "Jan 2017".
Isowo yii sii ijabo VAT fun {0}.
{0} will be a time period, like "Jan 2017".
Isowo yii gba isanwo fun Iwe iye-owo oja ti o njade#{0:N0}.
Isowo yii san {0}.
Isowo yii san iwe iye-owo oja ti nwọle #{0:N0} lati {1}.
Isowo KO PEYE: iye ti o sonu
Akoole
P&L fun {0} fun
The {0} is the organization name. The year number follows this string.
EreAdanu
Must ONLY contain A-Z, a-z characters - nothing accented!
The P&L jẹ àpapọ alaye ti owo ti o wole ati awon inawo, eyi ti o je kikojọpọ nipasẹ awọn isuna tabi iye owo / iru owo ti o wole. Apapo gbogbo owo ti o wole ati inawo jẹ esi ọdọọdun. O tun le fẹ lati wo balance sheet eyi jẹ àpapọ alaye awon ohun ini ati awọn gbese.
Odun to lo
Ikede Ere ati Adanu
Awon esi
Footer on P&L statement
YTD
Year To Date
Ti o ba jẹ pe iwe iṣowo rẹ ni Swarmops ti kuro ni ìsiṣẹpọ pẹlu awọn itan akọọlẹ banki rẹ fun eyikeyi idi imọran tabi eniyan, o le ṣe atunṣe ìsiṣẹpọ wọn nibi nipa gbigbe faili oga kan ga ti o bo akoko ti o nilo lati satunṣe ìsiṣẹpọ.

Ikilo: Eyi jẹ ilana ti o ma n gba akoko ti o le ṣe pupo awon ayipada si iwe iṣowo rẹ. Maṣe lo ayafi ti o ba ti ṣawari iyatọ ninu awọn itan akọọlẹ si banki rẹ.

(O ma ni anfani lati ṣe atunyẹwo awọn ayipada ti a gbero tẹlẹ ṣaaju ki wọn to di fifi si inu awọn akosilẹ owo rẹ.)
Satunṣe ìsiṣẹpọ Akoole Banki
Isuna, Eniti o ni
Displayed above editables
Eyi ni ibi ti awọn eto isuna ipile ti ma n je siṣeto fun isuna ọdun kọọkan. Lẹhin ti awọn wọnyi ti wa leto, ọkọọkan awon ti o ni isuna se atunpin awon owo laarin awọn igi isuna wọn.
Isuna Ipile Fun {0}
The {0} is replaced with the organization's name.
Seto Awon isuna Ipele Ipile
Displayed above main content
Seto Awon isuna Tuntun
Text on submit button
Owo ori Afikun
If applicable, translate to local legal tax term
Owo ori Iyokuro
If applicable, translate to local legal tax term
Apapọ Owo oya
Wo awọn iwe owo ori (awọn fọọmu owo ori ti o ti pari) fun iwe isanwo ajo naa, eyi ti o rọrun fun ọ lati daakọ si awọn fọọmu owo ori rẹ gangan, tabi boya tẹjade paapaa bi o ṣe wa. Iṣẹ-ṣiṣe ati awọn fọọmu gangan yatọ nipasẹ orilẹ-ede ati nigbamiiran ma da lori koodu third-party ati awon plugin.
Awọn fọọmu Owo ori Iwe isanwo
Awọn fọọmu Owo ori Oṣooṣu Fun
The {0} is the organization name. A country selector follows (imagine a "France" tacked on to the end).
Apapo Iye
Apapo Owo ori
Ikede Akoole
Akoole Banki
Aworan Banki
Displayed as header above modally zoomed screenshot

(Awọn data to tuntun julọ ni Swarmops ni {0} wa lati {1:yyyy-MMM-dd}. O yẹ ki o gba data banki lati o kere ju {2:yyyy-MMM-dd}.)
Displayed to help user determine scope of bank download

(PayPal ma sọ akoko ti o ti gba idunadura gbẹhin. Gba gbogbo awọn ijabọ idunadura lati aaye akoko naa, fifi bi ọjọ mẹta sẹyin kun.)
Displayed instead of date of last transaction in the case of Paypal.
Banki Gba Awọn ilana
Header above instructions for generation of the bank file type selected.

Faili naa ni awọn iṣowo {0:N0}. {1:N0} awọn iṣowo ti jẹ gbigbe pẹlu aseyori si {2} akọọlẹ iwe iṣowo. ({3:N0} Awọn isowo jẹ ẹda.)

Sibẹsibẹ, iṣiro banki ko baramu pelu awọn akosilẹ ni Swarmops. Eyi maa n jẹ bẹ nitori awọn iṣowo ti o sonu. Jọwọ ṣagbega akojọpọ iṣowo kan pẹlu akoko ti o tobi si lati ri daju pe Swarmops ri gbogbo awọn isowo.

Akọọlẹ iwe iṣowo Swarmops lọwọlọwọ kosi ni ìsiṣẹpọ pẹlu ti banki.

Displayed when import successful, but end balance out of sync. Assumes plural along all pasted numbers.

Faili banki ko se gbe wọle.

Eyi ni ọkan ninu awọn idi mẹta: o padanu diẹ ninu awọn apejuwe ninu ilana dawunlodi, banki naa ti yi ọna rẹ pada, tabi o ti gbe faili ti ko tọ rara
ga lairotẹlẹ (bi aworan kan lati inu ayeye ti o ṣe gbẹhin dipo awọn akojọ iṣowo). Awọn isowo kankan ko je gbigbewọle rara. Jọwọ tun gbiyanju.
Ko si awọn akọọlẹ dukia ti a ṣeto fun adaṣiṣẹ, nitorina ko si awọn akọọlẹ kankan to satilẹyin gbigbe data ga ni akoko yii. Pada si Dasibọdu.
Faili ti a nreti
The name of the expected file for uploading.
Faili ti je Gbigbe wole pelu Aseyori
Displayed as header after successful processing
Faili ti je Gbigbe wọle, Ṣugbọn Data ti Kuro ni Isiṣẹpọ
Displayed as header after a good processing that ended in sync failure
Iru Faili
can be Account Statement or Payments File
Asise lori gbigbe faili wole
Displayed as header on import failure

Faili naa ni {0:N0} awon isowo. {1:N0} awon isowo ti je gbigbe wole pelu aseyori si inu {2} akọọlẹ iwe iṣowo. ({3:N0} awọn isowo jẹ ẹda.)

Lẹhin ti o gbe wọle, iṣiro akọọlẹ ni Swarmops ba ti banki mu.

Displayed on successful import. Assumes plural among all pasted numbers.
Nibi, o le gbe awọn faili lati banki rẹ tabi olupese isanwo ga sinu iwe iṣowo ajọ rẹ. Awọn apẹẹrẹ pẹlu ni akoole ati awọn isanwo ti a gba.
Displayed in sidebar on page.
Awọn ilana
Gbe Awọn faili Banki ga
Displayed above main content.
Sibẹsibẹ, gbogbo wọn jẹ ẹda ti alaye isanwo ti a ti gbega tẹlẹ. Ko si gbigbe wole alaye isanwo tuntun kankan si Swarmops.
kosi isanwo|isanwo kan|awon isanwo {0}
none|one|many
Faili Isanwo ti je Gbigega
kosi awon akojọpọ isanwo|akojọpọ isanwo kan|awon akojọpọ isanwo {0}
none|one|many
Faili Awon isanwo
Faili isanwo naa ni {0}.
{0} {1:N2} ni awon isanwo je gbigbe wole, ti o je pinpin lori {2} kọja {3}.
like EUR 2,102.00 in 3 payments across 2 groups
Awọn ẹda alaye diẹ naa wa ({0} kọja {1}).
Nṣaayan Faili...
Iṣaayan ti Pari

Faili naa ko se ka bi faili atẹwole si banki yii.

Awọn idi pupọ ni eyi fi le ṣẹlẹ: faili naa le ti bajẹ, banki le ti paarọ ọna faili rẹ laipariwo, tabi o ti gbe faili ti ko tọ rara ga. Jọwọ gbiyanju lẹẹkansi.

Displayed when the input file can't be parsed, before import attempt.

Faili naa ti je gbigbe wole pelu aseyori. {0:N0} awọn isowo tuntun ti di gbigbe wọle; {1:N0} won je sisonu bi awọn ẹda awọn ohun ti o ti wa ni Swarmops tẹlẹ. Iṣiro akọọlẹ ni Swarmops ba ti banki mu.

Faili naa ni awọn iṣowo lati {2:yyyy-MMM-dd} si {3:yyyy-MMM-dd}.

Zero is new transaction count, one is duplicate transaction count, two and three are lowest and highest dates found in file. Pay attention to date format and adjust to culture.

Faili awọn isanwo naa jẹ gbigbe wole pelu aseyori. {1:N0} (awọn) isanwo ni {0:N0} (awọn)akojọpọ, ti apapọ {3} {2:N2}, jẹ gbigbe wole.

Arguments 0-3 in order: 0 PaymentGroupCount, 1 PaymentCount, 2 PaymentAmountTotal, 3 Currency

Faili isanwo naa jẹ gbigbe wole pelu aseyori. {1:N0} (awọn) isanwo ni {0:N0} (awọn)akojọpọ, ti apapọ {3} {2:N2}, jẹ gbigbe wole.

(Bakannaa ẹda (awọn) isanwo {5:N0} na tun wa ni {4:N0} (awọn)akojọpọ.)

Arguments 0-5 in order: 0 PaymentGroupCount, 1 PaymentCount, 2 PaymentAmountTotal, 3 Currency, 4 DuplicatePaymentGroupCount, 5 DuplicatePaymentCount

Faili naa je gbigbe wọle, ṣugbọn abajade iṣiro akọọle naa ko baamu.

Lẹhin gbigbe wọle {0:N0} awọn isowo (ati sisọnu {1:N0} awọn ẹda), gbogbo faili naa ti je yiyanju. Sibẹsibẹ, abajade isiro akọọle ni Swarmops kii ṣe bakanna bi ti ikede banki naa; iyatọ ti {3} {2:N2} kan wa.

Jọwọ ṣe igbiyanju lati ṣagbega ikede akọọle tuntun kan. Ti iyen ba si mu aibamu waye, o le nilo lati gbiyanju ṣatunṣe ìsiṣẹpọ akọọle banki naa pẹlu asọye faili ikede akọọle kan.

Displayed on successful import, but the resulting balance is off compared to the account statement file that was just uploaded. 2 is the diff, 3 is the currency.
Yan Akọọlẹ Iwe iṣowo
Select prompt for the financial account in the organization's bookkeeping.
Yan Iru Faili Ati Akọọlẹ Fun Gbigbega
Yan Iru Faili Banki
Header above several bank logos, prompting a selection of bank.
Gbe faili banki miran ga?
Displayed as header after uploading one file
Gbe faili Banki ga
Displayed as header above download instructions / upload form
Iyatọ
Isiro Leja
Apapo
Igbese
keep short
Iye
keep short
Apejuwe
Inawo Titipa
keep short
ID#
keep short
Ọjọ ti o je ṣisi
keep short
Olugba
Akojo ti ko ti yanju
Oju iwe yii ma n jẹ ki o ṣe ijẹrisi awọn akọọle ti gbese ati eyi ti ko ti yanju (awon inawo, awon iwe iye-owo oja, awon owo agbaalẹ, etc.) ni aaye ti lọwọlọwọ ni akoko yii tabi ni akoko ipade ti eyikeyi lẹja ti tẹlẹ.
Ṣe akojọ Awọn akọọle ti ko ti yanju
-- ko si nkankan lati jabọ --
This is displayed when there are no items at all in a VAT report.
Awọn apapọ Ijabọ
Deeti/Akoko
Timestamp of transaction
Apejuwe
Description of transaction
Awon iwe
This is above the "view documents" icon
VAT ti nwọle
Ko si awọn ijabọ VAT fun ajọ yii
VAT ti njade
Owo isowo
O n wo ijabọ VAT ti a fi se eto. Awọn VAT ti nwọle ati ti o njade jade, ati ti apapọ owo isowo, ti jẹ kikọ silẹ fun akoko ijabọ naa. Ijabọ yii ṣetan lati jẹ fifiransẹ si awọn alaṣẹ owo-ori.
Kosi awọn ijabọ VAT kankan lati safihan. Eleyi le jẹ nitori wipe akoko ijabọ VAT ni kikun ko ti pe tan, nitorina ko ti ṣee ṣe lati ṣeda ijabọ kan na.
Awọn ijabọ VAT
VAT is short for Value Added Tax; it has completely different names in different EU countries (moms, Umsatzsteuer, etc.)
Awọn apapọ fun ijabọ yii
Displayed as description of footer
Wo
This is the word or words before the name of the displayed VAT report.