text/microsoft-resx 2.0 System.Resources.ResXResourceReader, System.Windows.Forms, Version=4.0.0.0, Culture=neutral, PublicKeyToken=b77a5c561934e089 System.Resources.ResXResourceWriter, System.Windows.Forms, Version=4.0.0.0, Culture=neutral, PublicKeyToken=b77a5c561934e089 Ti o ba fẹ lati kopa siwaju si, o le pese ara rẹ fun awọn ipe-si-iṣẹ, ni aisi ọranyan kankan lati han, lọ, tabi kopa ninu pato eyikeyi ninu wọn. {0} Ni anfaani {0} is the Activist label for the org. Bawo ni o se nifẹ lati kopa to? Ọpọlọpọ oriṣiriṣi ipele wa ti o le gba kopa ni {0}. Yan ipele ipinnu rẹ ni isalẹ (eyi ti o le yipada bi o ba se wu ọ ti o ba ya, dajudaju): {0} is the org name. Eyi ni ipele atilẹba, o tumọ si pe o ma kopa deede ninu ajọ naa bi ti awọn ẹsẹkuku {0}. {0} is the Participantship name (membership, ambassadorship etc). Eyi ni ipele atilẹba, eyi ti o tumọ si pe o le ṣe ikopa bi o ṣe fẹ (tabi rara) bi {0} lakoko ti o nduro de {1} rẹ. Rẹgula {0} {0} is the Regular Participant label for the org. Ti o ba fẹ lati jọwọ ara rẹ fun iṣẹ ṣiṣe aigbafẹ fun abala kan ti ajọ naa, sise iranwọ nibi ti o ti jẹ ninilo julọ, o jẹ titẹwọ julọ. (O ma gba asayan awọn ipo ti o le jọwọ ara rẹ fun ni ojuewe ti o tẹle eyi.) Ofisa Olujọwọ ara ẹni O n fi ibẹwẹ kan silẹ fun {0} pẹlu {1}. Ko si owo ti o nii ṣe fifi iru ibẹwẹ bẹ silẹ. Nbeere fun {0} ni {1} Kaabọ! Eyi ni <em>Dasibọdu,</em> nibi ti o ti le wọle si awọn iṣiṣẹ inu ti {0}. O ma gba alaye diẹ sii ni meeli ni aipẹ.<br/><br/> Ti o ba ti jọwọ ara rẹ fun iṣẹ ṣiṣe aigbafẹ, ẹnikan (boya olujọwọ ara ẹni kan naa, bi ara rẹ) ma kan si ọ lati jiroro diẹ sii nipa awọn aaye ti o wa. Eyi ni akanṣe ọrọ ikini ku aabọ ajọ naa. Ko ti jẹ kikọ; o ma n jẹ ṣiṣeto ni Iseto Abojuto / Ajọ. Eyi ni pato ọrọ ajọ naa ti o ma n jẹ fifihan fun Amudopin Iforukosilẹ. O ma n jẹ ṣiṣeto ni Iseto Abojuto / Ajọ. Nigba ti eniyan tuntun naa ba tẹ Pari, wọn ma jẹ gbigba sinu ajọ naa, wọle si, ati jẹ fifiranṣẹ si Dasibodu naa gẹgẹbi olumulo Alakọbẹrẹ. Eyi ni alaye nipa ila ẹgbẹ kekere ti ajọ naa. O ma n jẹ ṣiṣeto ni Iseto Abojuto / Ajọ. O ti forukọsilẹ tẹlẹ si iṣakoso Swarmops yii. Jọwọ lo iṣẹ Atunto Ọrọ igbaniwọle lati oju ewe iwọle dipo ṣiṣẹda akọọlẹ tuntun kan. Jọwọ yan ati ki o tun ọrọigbaniwọle kan tẹ. Awọn ẹda ọrọ igbaniwọle mejeji ko baramu. Jọwọ yan ipele iṣẹ ṣiṣe ti o fẹ. Jọwọ yan o kere ju ipo kan. Awọn owo ati Awọn iye owo Ko si iye owo kankan lati forukọsilẹ fun {0} {1}. Sibẹsibẹ, owo wa ma wa lati se isọdọtun {1} nigbati o ba dopin ni {2}. Iye naa jẹ {3} lọwọlọwọ {4:N2}, ati pe o ko si labẹ ọranyan lati se isọdọtun. {0} {1} is duration and Participantship, like "one-year Membership". {2} is the projected expiration date. {3} {4} is the renewal fee as it's currently set (NB: it may be different when the date is reached). Owo {0} naa jẹ {1} {2:N2} fun {3}. O ma gba iwe iye-owo oja ni opin ilana yii. (O le fi opin si {0} rẹ ni eyikeyi akoko.) {0} is the Participantship title. {1} and {2} are the currency and amount. {3} is the duration, like "one year" or "two years" (set in Organization Settings). Se imudopin Iforukọsilẹ Iwọle rẹ (meeli rẹ) Ko si iye owo kankan ninu fiforukọsilẹ fun {0} pẹlu {2}, tabi eyikeyi iye owo lati ṣe isọdọtun nigbati o ba dopin ni {1}. Ni afikun, o le fopin si {0} rẹ ni eyikeyi akoko. {0} is the Participantship title. {1} is the expiry date. {2} is the organization name. Yan ọrọ igbaniwọle kan Tun ọrọ igbaniwọle naa tẹ Nforukọsilẹ fun {0} The {0} is the organization name Kaabọ! Afihan kukuru kan Nipa rẹ Sọ nkan diẹ nipa ara rẹ fun wa? Ṣẹda Iwọle Mu ọrọ igbaniwọle kan Iṣẹ 1 Bawo ni o se nifẹ lati kopa to? Iṣẹ 2 Kini o nifẹ lati kopa ninu? Pari Isanwo Gbogbo ẹ ti pari. Jẹ ki a wọle! Jẹ ki a san owo {0} ki a si pari! The {0} is Membership, Ambassadorship, etc. The Regularship label for this organization. Pari Iforukọsilẹ. Ipo wo ni o nifẹsi? Agbegbe To ga julọ To wa Ipo Ṣayẹwo ipo ti o fẹ lati jọwọ ara rẹ / beere fun. O le ṣayẹwo ọpọlọpọ. Kaabọ si {0} The {0} is the organization name Iwọle rẹ Jọwọ yan ọrọ igbaniwọle lati wọle si Swarmops (eto yii). O ma ni anfaani lati rọpo eyi pẹlu iwọle Twitter, Facebook, tabi BitID fun irọrun ti o ba ya. Orukọ rẹ