text/microsoft-resx 2.0 System.Resources.ResXResourceReader, System.Windows.Forms, Version=4.0.0.0, Culture=neutral, PublicKeyToken=b77a5c561934e089 System.Resources.ResXResourceWriter, System.Windows.Forms, Version=4.0.0.0, Culture=neutral, PublicKeyToken=b77a5c561934e089 Iwọle si ojuewe yii ti jẹ kikọ O gbiyanju lati wọle si ojuewe ti o ko ni awọn igbanilaaye fun. Wo panẹẹli akọkọ fun awọn idi ti eyi le fi ṣẹlẹ. Iwọle jẹ Kikọ
Awọn eto ilana aabo Swarmops ti kọ iwọle rẹ si ojuewe ti o n gbiyanju lati lọ si. Eyi saba tumọ si pe awọn iṣẹ rẹ ga ju awọn ipele wiwọle ti a fifun ọ lọ fun ajọ ti o yan lọwọlọwọ ({0}). Eyi ko ti wa ni igbasilẹ tabi jẹ jijabọ nibikibi.

Awọn idi pupọ ni idi ti eyi le fi ṣẹlẹ:
Ajọ lọwọlọwọ yii O le ma kopa ninu awọn ọpọlọpọ ajọ lori isàgbékalẹ̀ Swarmops yii. Eyi ni ibi ti o ti ma se iyipada laarin wọn. Ajọ Tuntun O ko kopa ninu eyikeyi ajọ miiran ti o wa lori isàgbékalẹ̀ Swarmops yii, nitorina o ko le yipada si nkan miiran. Nitorina, a n pada lọ si Dasibodu dipo. Se ayipada Awọn ajọ Yipada Agbega Ibi ipamo data wa ni Asorọ Ojuewe yii nilo ibi ipamo data Swarmops ti o ti ni igbesoke. Nduro de Agbesoke Ibi ipamo data
Aṣorọ igbesoke data kan wa ti o se idilọwọ wiwọle rẹ si ojuewe yii. Eyi jẹ ipo onigbadiẹ atipe awọn iṣakoso Swarmops gbọdọ ti bẹrẹ isẹ lori ṣiṣe agbega ti o yẹ.

Gbiyanju lati lọ ojuewe naa ni iṣẹju diẹ. Ti o ba si wa ni ipo naa ju iṣẹju mẹẹdogun lọ, kan si alakoso eto rẹ.
Akọọlẹ naa ko jẹ titipa. Kosi iru akọọlẹ bẹẹ, tabi iwe ọja naa ko fẹsẹmulẹ tabi ti pẹ ju. Ti o ba tun fẹ lati ti akọọlẹ yii pa, kan si awọn alakoso ti iṣàgbékalẹ̀ Swarmops yii. Ti o ba n ri ojuewe yii, o n gbiyanju lati ti akọọlẹ olumulo kan pa fun awọn idi aabo. Ti itọkasi naa ba sisẹ ti ko ti jo tan, akọọlẹ naa ti wa ni titipa. Atipa Akọọlẹ Olumulo Akọọlẹ naa ti jẹ titipa pẹlu aseyọri ti eyikeyi awọn akoko iṣiṣẹ ti nṣiṣẹ lọwọ jẹ fifopin si. Tikẹti Atipa AWON LEJA SISI

{0} n lo awọn lẹja siṣi. Eyi tumọ si pe ẹnikẹni le ṣayẹwo awọn ijabọ owo ati iwe iṣowo. O ti wọle sori awọn isẹ ti ajọ naa lati ṣe eyi gangan. The {0} is the organization name. Ifọwọsi ifosiwẹwẹ-meji ti BitID ti wa ni mimu ṣiṣẹ bayii.

Lati isinyi lọ, o le lo apo owo bitcoin rẹ lati wọle (atipe wa nilo lati ṣe bẹ). O ṣeun fun ṣiṣe imuṣiṣẹ afikun aabo.

Jọwọ ranti lati tọju foonu rẹ pẹlu aabo ọrọ igbaniwọle, pẹlu. NILO IWOLE BITID

Iwọle yii nilo ìfàṣẹsí BitId, bi o ti jẹ mimu ṣiṣẹ nipasẹ ẹniti ti o di akọọlẹ mu. O ko le wọle pẹlu akanpọ orukọ olumulo/ọrọ igbaniwọle. 2FA Tẹ koodu rẹ lati Google Authenticator. Wọle pẹlu Ibuwọlu Bitcoin (BitId) Iranwọ Wọle si Swarmops nipa lilo apo owo bitcoin rẹ ti o ni imusisẹ bitid. O ko nilo owo kankan ninu rẹ. Ti o ko ba ni apo owo bitcoin ti o ni imusisẹ bitid, o le wọle pẹlu afọwọyi pẹlu lilo orukọ olumulo ati ọrọ igbaniwọle. (Orukọ olumulo rẹ jẹ orukọ rẹ tabi imeeli.) Nwọle sinu, Jọwọ duro... Iwọle ti Ọrọ igbaniwọle Afọwọyi Header to manual username/password form Wọle Kọja Egbami, Mo gbagbe ọrọ igbaniwọle mi! Forukọ mi silẹ fun {0}! {0} is the organization name. Nwa lati Darapọ? Swarmops ko da adirẹẹsi yii mọ. Jọwọ wọle pẹlu afọwọyi ki o si mu adirẹẹsi rẹ ṣiṣẹ ṣaaju ki o to lo lati wọle. Lo ifọwọsi ifosiwewe-meji ti BitID? Switches from manual to BitID Lo iwọle ọrọ igbaniwọle afọwọyi? Switches from BitId to Username/Password form Olumulo Ko si tikẹti atunto ọrọ igbaniwọle ti o fẹsẹmulẹ fun adirẹsi imeeli yii, adirẹẹsi naa kosi, tikẹti atunto ọrọ igbaniwọle naa ko fẹsẹmulẹ, tabi o ti jotan.

Atunto ọrọ igbaniwọle kuna. O n ṣatunkọ ọrọ igbaniwọle fun akọọlẹ olumulo kan. Tẹ ọrọ igbaniwọle rẹ lẹẹmeji lati ṣeto rẹ ki o si wọle. (Ti o ba n gbiyanju lati bẹrẹ ilana atunto-ọrọ igbaniwọle, o nilo tikẹti lati ṣe bẹ. Ṣẹda tikẹti kan.) Tẹ adirẹẹsi imeeli rẹ lati gba awọn itọnisọna bi o ṣe le tẹsiwaju pẹlu ilana atunto ọrọ igbaniwọle. Awọn itọnisọna naa yoo ni koodu adayatọ kan ti o ma jo tan ti o ma nilo lati tẹsiwaju. Tẹ adirẹẹsi imeeli rẹ Se atuntẹ adirẹẹsi imeeli rẹ Awọn ọrọ igbaniwọle mejeeji naa ko baramu. Jọwọ tun gbiyanju. Ọrọ igbaniwọle tuntun ko le jẹ ofo. Ṣàtúntò ọ̀rọ̀ ìgbaniwọ́lé Ọrọ igbaniwọle tuntun Tun Ọrọ igbaniwọle Tuntun tẹ O le satunto ọrọ igbaniwọle ti o ni ajọṣe pẹlu adirẹẹsi meeli kan. Itọkasi kan ti o ni koodu tikẹti kan ma jẹ fifiranṣẹ si adirẹẹsi imeeli naa, eyi ti o gbọdọ tẹle lati ṣatunto ọrọ igbaniwọle rẹ. Satunto Ọrọ igbaniwọle rẹ jẹ yiyipada atipe o ti wọle si Swarmops nipa lilo ọrọ igbaniwọle tuntun rẹ. Tikẹti Ti adirẹẹsi meeli naa ba ni ajọṣe pẹlu akọọlẹ kan lori iṣàgbékalẹ̀ Swarmops yii, tikẹti atunto kan ti jẹ fifiranṣẹ. Ṣi imeeli yẹn ki o si tẹ itọkasi inu meeli naa lati satunto ọrọ igbaniwọle rẹ. (Ti ko ba si imeeli naa, nkankan ko jẹ fifiranṣẹ.)

O le pa taabu aṣàwákiri yii de. Ko niwulo mọ.