text/microsoft-resx 2.0 System.Resources.ResXResourceReader, System.Windows.Forms, Version=4.0.0.0, Culture=neutral, PublicKeyToken=b77a5c561934e089 System.Resources.ResXResourceWriter, System.Windows.Forms, Version=4.0.0.0, Culture=neutral, PublicKeyToken=b77a5c561934e089 A nilo ilu ti o fẹsẹmulẹ. Pese ọjọ ti o fẹsẹmulẹ tabi fi aaye yii silẹ lofo. A nilo imeeli ti o fẹsẹmulẹ. A nilo orukọ kan. A nilo opopona tabi apoti ile-ifiweranṣẹ ti o fẹsẹmulẹ. Ti ṣawari agbegbe Eyi ni ibi ti o ti ma ko awọn eniyan tuntun sinu ajọ. Bi o ṣe forukọ wọn silẹ fun <strong>{0} {1}</strong> titi di <strong>{2}</strong>, wọn ma gba ifiranṣẹ ikini ku aabọ pẹlu ọrọ igbaniwọle alaileto iwọle kan ninu meeli. Awọn ọfisa ibilẹ naa ma wa ni ifitonileti nipa eniyan tuntun naa, fun anfaani lati fi ifiranṣẹ ikini ku aabọ ranṣẹ si wọn. {0} and {1} can be "one-year" and "Membership", for example. {2} is LongDateString. Idanimọ ti ẹya oju-ara "Legal" to cut short discussions on 50 different genders for the time being Afikun eniyan naa ni si ajọ naa waye pẹlu aseyọri. Meeli ikini ku aabọ kan ti jẹ fifiranṣẹ. Awọn Data iṣiro Header for gender, date of birth Opopona 1 (tabi apoti ile-ifiweranṣẹ) Opopona 2 - ti o ba wa Fi kun {0} The {0} is replaced in code. Singular form gender neutral of Participant. Lo eyi lati wa awọn eniyan ninu ajọ naa. O le se wiwa nipasẹ agbegbe ati nipa ilana eto orukọ ("Jo S" ma ba Joel Sander mu). Siso awọn eniyan pọ ni {0} The {0} parameter is the organization name. Ilana eto Orukọ Ṣe akojọ ki o si Wa Awọn eniyan Awon eto esi naa ni ju ẹgbẹrun eniyan lọ (ifihan jẹ dindinku si iwọnba ẹgbẹrun kan). Jọwọ ṣe atunse àwárí rẹ? Ajọ Ibilẹ ({0}) Ajọ Agbaye naa Awọn wọnyi ni awọn olubasọrọ ibilẹ rẹ. (Ti o ba ni awọn anfaani isakoso, o tun le fi awọn eniyan si awọn ipo wọnyi.) Ajọ Ibilẹ Mi The {0} is the geography name. Yan eniyan... Ṣẹda ipo tuntun...